Education resource centreDownload 3.49 Mb.
Page25/47
Date29.01.2017
Size3.49 Mb.
#11609
1   ...   21   22   23   24   25   26   27   28   ...   47

YORÙBÁ SS 1 TÁÀMÙ KEJÌ

ÕSÊ

ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ

ÀMÚŚE IŚË


1

ÈDÈ: Àkàyé:

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Ôgbön tí a ń ta fún àśeyege lórí àkàyé

b. Kíka àyôkà

d. Títúmõ àkànlò èdè, òwe àti ônà èdè tí ó jçyô nínú àyôkà ní ìbámu pêlú bí a ti lò ó.

e. Dídáhùn ìbéèrè lórí àkóónú àyôkà


OLÙKÖ:

Śe àwárí àwôn àyôkà tó jçmö õrõ tó ń lô. Irú àyôkà bëê gbôdõ ní ìlò èdè tó dára. 1. Jë kí akëkõö ka àyôkà náà dáradára

d. Tö akëkõö sönà láti dáhùn ìbéèrè nípa àyôkà

e. Tö akëkõö sönà láti sô ìtumõ òweAKËKÕÖ:

 1. Tëtí sí àlàyé lórí àkàyé

 2. Ka àyôkà, dáhùn àwôn ìbéèrè lórí rê

d. śe àlàyé ìtumõ òwe, àkànlò èdè tí ó súyô ní ìbámu pêlú bí a śe lò wön.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

Àyôkà oríśiríśi tí ó dá lé ìśêlê àwùjô.2.

LÍTÍRÈŚÕ: Àtúpalê àsàyàn ìwé eré-onítàn (ìwé méjì)

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Kókó Õrõ

b. Àhunpõ Ìtàn

d. ibùdó ìtàn

e. Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá

ç. Ìlò èdè

f. Àmúyç àti àléébù


OLÙKÖ:

a. jë kí akëkõö ka ìwé ìtàn eré-onítàn 1. Śe àlàyé kíkún lórí ìjçyô àkóónú iśë nínú eré-onítàn àsàyàn:

 1. Kókó õrõ

ii. Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá

 1. ibùdó ìtàn

 2. ìlò èdè

 3. ìjçyô àśà abbl

d. kô àwôn õrõ pàtàkì tí ó súyô sórí pátákó, kí o sì śàlàyé ìtumõ wôn.

e. Béèrè ìbéèrè löwö akëkõöAKËKÕÖ:

a. Ka ìwé eré-onítàn wá láti ilé àti nínú kíláásì

b. Tëtí sí àlàyé olùkö

d. Kô àwôn õrõ tí olùkö kô sí orí pátákó sínú ìwé.

e. Dáhùn ìbéèrè olùkö

OHUN-ÈLÒ:


 • Ìwé eré-onítàn

3.

ÀŚÀ: Àśà ìsômôlórúkô ní ilê Yorùbá

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Ìgbàgbö Yorùbá nípa pàtàkì orúkô (orúkô ômô ni ìjánu ômô)

b. Ètò ìsômôlórúkô b.a ifá lômô

d. Oríśiríśi orúkô àti ìtumõ wôn.

i. Àbisô

ii. Àmútõrunwá

iii. Oríkì

iv. Ìnágijç

v. Ìdílé

vi. Òde-òní abbl
OLÙKÖ:

 1. Kô oríśiríśi orúkô sí ojú pátákó

 2. Śàlàyé pàtàkì orúkô àti oríśiríśi orúkô

d. Śàlàyé orúkô òde oni

e. Darí àwôn akëkõö láti śe ìjìnlê eré ìsômôlórúkô.AKËKÕÖ:

a. Tëtí sí àlàyé olùkö

b. sô ohun tí wôn mõ nípa ìsômôlórúkô sáájú ìdánilëkõö

d. sàwòkô orúkô tí ó wà lára pátákó

e. kópa nínú ìśeré, ìsinjç ìsômôlórúkô.

ç. śe àdàkô àwôn lëtà ìró köńsónáýtì àti fáwëlì naa.OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

1. Ohun èlò ìsômôlórúkô: oyin, atare, orógbó, obì, çja, omi

2. Kádíböõdù tí a to orúkô ômô àti ìtumõ wôn sí.


4.

ÈDÈ: Aáyan Ògbufõ

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Ìtösönà lórí bí a śe ń śe aáyan ògbufõ

b. Túmõ àwôn gbólóhùn kéékèèké láti èdè Gêësì sí Yorùbá


OLÙKÖ:

a. Śàlàyé bí a śe ń śe aáyan ògbufõ

b. Túmõ àwôn gbólóhùn láti èdè Gêësì sí Yorùbá

d. Kô àwôn gbólóhùn àti àkànlò èdè tí a túmõ sí orí pátákó.AKËKÕÖ:

a. Tëtí sí bí olùkö śe ń túmõ àwôn gbólóhùn

b. Kô àwôn gbólóhùn àti àkànlò èdè tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé wôn.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:


 • Pátákó ìkõwé

5.

LÍTÍRÈŚÕ: Àtúpalê ìwé ìtàn àròsô (ìwé méjì)

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. kókó õrõ

b. ìfìwàwêdá

d. Àhunpõ ìtàn

e. Ibùdó ìtàn

ç. ôgbön ìsõtàn

f. êdá ìtàn

g. ìlò èdè

gb. Ìjçyô àśà

h. Àmúyç àti àléébùOLÙKÖ:

a. Jë kí akëkõö ka ìwé ìtàn àròsô.

b. Śe àlàyé ní kíkún lórí ìjçyô àkóónú iśë lórí ìwé ìtàn: kókó õrõ, ìfìwàwêdá, àhunpõ ìtàn, ibùdó ìtàn, ôgbön ìsõtàn, àmúyç àti àléébù.

d. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì tó súyô sójú pátákó kí ó sì śàlàyé ìtumõ wôn.AKËKÕÖ:

a. Ka ìwé ìtàn àròsô wa láti ilé àti nínú kíláásì.

b. Tëtí sí àlàyé olùkö

d. Kô àwôn õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé.OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

Ìwé ìtàn àròsô6.

ÈDÈ: Àkànlò Èdè

ÀKÓÓNÚ IŚË:

a. Oríkì àkànlò èdè

b. Oríśiríśi àkànlò èdè

d. Ìlò Àkànlò èdè
OLÙKÖ:

a. Sô ìtumõ àkànlò èdè

b. Jë kí akëkõö sô ìtumõ àwôn àkànlò èdè.

AKËKÕÖ:

a. Tëtí sí àlàyé olùkö

b. Sô oríśiríśi àkànlò èdè

d. Sô ìtumõ àkànlò èdèOHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 • Ìwé àkànlò èdè pêlú ìtumõ wôn

 • Pátákó ìkõwé

7.

ÈDÈ:

a. Àròkô kíkô

b. Ìgbésê fún àròkô kíkô

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Oríkì àròkô

b. Àwôn ìgbésê tí a ń têlé láti kô àròkô kíkô

d. Oríśiríśi àwôn àròkô:

i. Àròkô aláríyànjiyàn

ii. Àròkô oníròyìn/ asõtàn

iii. Àròkô alálàyé

iv. Àròkô ajçmö-ìsípayá

v. Àròkô onísõrõýgbèsì

vi. Àròkô asàpèjúwe

vii. Lëtà Kíkô:

a. Lëtà gbêfê

b. Lëtà aláìgbagbêfê


OLÙKÖ:

a. Sô ìtumõ àròkô

b. Śàlàyé ìlapa èrò lórí àròkô kíkô

d. Tö akëkõö sönà láti kô àròkô

e. Yç ìśe akëkõö wò

AKËKÕÖ:

a. Tëtí sí àlàyé olùkö

b. Kô àwôn àlàyé ojú pátákó sílê

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:


 • Pátákó ìkõwé

8.

LÍTÍRÈŚÕ:

Àtúpalê àsàyàn ewì àpilêkô (ìwé méjì)ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Kókó oro

b. Ìhun ewì (ètò)

d. Ìlò èdè

e. Ijçyô àśà

ç. Àmúyç àti àléébùOLÙKÖ:

 1. Jë kí akëkõö ka ìwé àsàyàn ewì àpilçkô

 2. Śe àlàyé ní kíkún lórí ìjçyô àkóónú iśë nínú ìwé àsàyàn ewì àpilêkô:

 1. Kókó õrõ

 2. Ìhun ewì

 3. Ìlò èdè

 4. Ìjçyô àśà

 5. Àmúyç àti àléébù

d. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì, kí o sì śàlàyé ìtumõ wôn.

AKËKÕÖ:

a. Ka ìwé àsàyàn ewì àpilêkô wá láti ilé àti nínú kíláásì

b. Tëtí sí àlàyé olùkö

d. Kô àwôn õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé.OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 • Ìwé àśàyàn ewì àpilêkô

9.

ÀŚÀ:

Àśà ìtöjú ara lóde òní àti ewu tí ó rõ mö ô.ÀKÓÓNÚ IŚË

 1. Ìtöjú ara çni b.a irun, èékánná, eyín, aśô:

 2. Ewu ìlòkulò oògùn olóró

d. ìtöjú ara lóde òní, àýfààní àti àléébù rê b.a

i. Ètè kíkùn

ii. irun díndín

iii. Ihò méjì lílu sí etí kan

iv. imú lílu

v. orin/ ewì nípa ìmötótóOLÙKÖ:

 1. Darí akëkõö láti sô õnà tí a lè gbà śe ìtöjú ara

 2. Śàlàyé ewu tó wà nínú àsìlò oògùn àti lílo oògùn olóró

d. Darí àwôn akëkõö láti kô orin/ ka ewì nípa pàtàkì ìmötótó

AKËKÕÖ:

 1. Sô ìrírí rç nípa ewu tí àìtöjú ara lè fà.

 2. Kô orin tàbí ka ewì tí ó dá lórí pàtàkì ìmötótó

d. Śe àpççrç àwôn tí ó ti lo ìlòkulò oògùn olóró pêlú àyôrísí rê.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

1. Pákò, búröõsì àti ôsç ìfôyín

2. Àwòrán õmùtípara, wèrè/ asínwín

3. Fíìmù tó śe àfihàn àtubõtán ìlòkulò oògùn àti oògùn olóró.10.

ÈDÈ:

Àwôn ìsõrí õrõ nínú èdè YorùbáÀKÓÓNÚ IŚË

 • Õrõ-orúkô

 • Õrõ-ìśe

 • Õrõ-aröpò orúkô

 • Õrõ-aröpò afarajorúkô

 • Õrõ-àpönlé

 • Õrõ-atökùn

 • Õrõ-àsopõ

OLÙKÖ:

 1. Sô oríkì ìsõrí õrõ

 2. Śe àlàyé bí a śe lè dá ìsõrí õrõ kõõkan mõ nínú gbólóhùn.

d. Kô àwôn ìsõrí õrõ náà sí ojú pátákó.

AKËKÕÖ:

 1. Tëtí sí àlàyé olùkö

 2. Kô àwôn ìsõrí õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé wôn

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 1. Ìwé girama òde òní

 2. Ìwé èdè-ìperí Yorùbá

 3. Àwòrán àtç aröpò-orúkô àti afarajorúkô
11.

ÀŚÀ:

Àwôn òrìśà ilê YorùbáÀKÓÓNÚ IŚË

Àwôn òrìśà ilê Yorùbá: 1. Ôbàtálá

 2. Õrúnmìlà

 3. Ògún

 4. Èśù

 5. Śàngó

 6. Egúngún

OLÙKÖ:

a. Śe àlàyé lórí àwôn òrìśà gëgë bí asojú Olódùmarè:

b. Śàlàyé kíkún nípa:

ìgbàgbö


oríkì

olùsìn àti abôrê

ìsìn (ojoojúmö, õsõõśê, ôdôôdún)

ohun èlò


èèwõ

ìmúra/ aśô abbl

d. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì sí ojú pátákó

AKËKÕÖ:

a. Tëtí sí àlàyé olùkö nípa àwôn òrìśà.

b. Kô àwôn õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé

d. kô ìparí àwôn òwe tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé wôn.OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

a. Àwòrán ojúbô àti abôrê

b. Àwôn ohun ètò fún ìsìn òrìśà b. a; aaja, kele Śàngó, ère òrìśà abbl


12.

ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ

13.

ÌDÁNWÒ

YORÙBÁ SS 1 TÁÀMÙ KËTA

ÕSÊ

ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ

ÀMÚŚE IŚË


1

ÀŚÀ: Oge Śíśe ní Ayé Àtijö àti Òde Òní

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Pàtàkì oge śíśe

b. Oríśiríśi õnà tí a ń gbà śoge ní ayé àtijö.


 • Ara fínfín

 • Eyín pípa

 • Tìróò lílé

 • Làalì/ osùn kíkùn

 • Irun dídì

 • Ilà kíkô àti bëê bëê lô

d. Irun fífá: irun gígê, irun dídì, irun kíkó

e. Bàtà wíwõ lóríśiríśi

ç. Ìyípadà tó dé bá àśà oge śíśe ní òde òní:


 • Ètè kíkùn

 • Irun díndín

 • Ihò méjì lílu sí etí kan

 • Imú lílu

 • Aśô tó fara sílê

 • Bàtà gogoro àti bëê bëê lô

OLÙKÖ:

a. Tö akëkõö sönà nípa ìdí tí àwôn Yorùbá fi ń śoge.

b. Śe àfihàn ohun èlò oge śíśe

d. Tö akëkõö sönà láti dárúkô irúfë oge śíśe tí ó wà ní òde òní àti àléébù tí ó wà níbê fún ôkùnrin àti obìnrin.AKËKÕÖ:

a. Sô ohun tí o ti śàkíyèsí nípa oge śíśe ní àwùjô àti ìdí pàtàkì tí àwôn ènìyàn fi ń śe oge.

b. Sô irúfë oge śíśe tí wön mõ mö obìnrin śáájú ìdánilëkõö

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:


 • Ohun èlò gidi tìróò, bèbè ìdí, ìlêkê, làálì, osun, wíìgì, lëêdì, èékánná

 • Àwòrán oríśiríśi irun dídì, irun gígé àti bëê bëê lô.

2.

ÈDÈ: Àròkô Ajçmö-Ìśípayá

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Kíkô àwôn ìlànà tí à ń gbà kô àròkô ajçmö-ìsípayá

b. Ìlapa èrò àròkô ajçmö-ìsípayáOLÙKÖ:

a. Śe àpççrç ìlapa èrò àkôlé àròkô ajçmö-ìsípayá kan lójú pátákó ìkõwé

b. Mú kí akëkõö śe ìlapa èrò àkôlé àròkô ajçmö-ìsípayá mìíràn

d. Tö akëkõö sönà láti kô àròkô nípa lílo àwôn ìlapa tí ç śe ní kíláásì.

e. Yç iśë akëkõö wò.

AKËKÕÖ:

a. Kíyèsí àpççrç ilapa èrò tí olùkö śe dáradára, sì dà á kô sínú ìwé rç

b. Śe ìlapa èrò tìrç mìíràn

d. Lo ìlapa méjèèjì tí ç śe ní kíláásì láti kô àròkô.OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 • Pátákó ikõwé

3.

ÌWÉ KÍKÀ: Àtúpalê Ìwé Eré-Onítàn

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Kókó õrõ:

b. Àhunpõ ìtàn

d. Ibùdó ìtàn

e. Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá

ç. Ìlò èdè

f. Ìjçyô àśà

g. Àmúyç àti àléébù
OLÙKÖ:

a. Jë kí akëkõö ka ìwé eré-onítàn

b. Śàlàyé ní kíkún lórí ìjçyô àkóónú iśë nínú ìwé eré-onítàn


 • Kókó õrõ

 • Àhunpõ ìtàn

AKËKÕÖ:

a. Ka ìwé eré-onítàn wá láti ilé àti nínú kíláásì.

b. Tëtí sí śàlàyé olùkö

d. Kô àwôn õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwéOHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 • Ìwé eré-onítàn

4.

ÌSÕRÍ ÕRÕ: Õrõ-orúkô

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Oríkì õrõ-orúkô

b. Oríśi õrõ-orúkô bí i: orúkô àdájë, orúkô àśeékà, orúkô aláìśeékà, orúkô afoyemõ àti bëê bëê lô.


OLÙKÖ:

a. Kô àpççrç àwôn õrõ tí à ń pè ní õrõ-orúkô, õrõ-orúkô bí i ilé, igi, ojú, Ayõ.AKËKÕÖ:

a. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí õrõ-orúkô

b. Kô àwôn àpççrç tí olùkö kô sókè

d. Pe àwôn õrõ náà bí olùkö śe pè é.OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

Kô àwôn àpççrç ìsõrí õrõ sí ojú pátákó/ kádíböõdù5.

ÈDÈ: Ìhun gbólóhùn nínú àpólà-orúkô, àpólà-ìśe, àpólà-atökùn

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Ìhun àpólà

b. Iśë tí àpólà ń śe nínú gbólóhùn

d. Àlàyé lórí oríśi àpólà tí ó wà: àpólà-orúkô, àpólà-ìśe, àpólà-atökùnOLÙKÖ:

a. Àlàyé lórí oríśiríśi àpólà tí ó wà

b. Fi iśë àpólà hàn nínú gbólóhùn

d. Śe àfihàn àpólà àti awë-gbólóhùnAKËKÕÖ:

a. Fi àpólà gbólóhùn wé awë-gbólóhùn láti lè mô ìyàtõ tó wà láàrin wôn

b. Śe àpççrç àpólà oríśiríśi tí ó wà.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:


 • Pátákó ìkõwé

 • Kádíböõdù tí ó ní àkôsílê àpólà õrõ-orúkô, àpólà atökùn, àpólà-ìśe.

6.

ÌSÕRÍ ÕRÕ: Õrõ-Ìśe

ÀKÓÓNÚ IŚË:

Ìsõrí õrõ: õrõ-orúkô, õrõ-aröpò orúkô, õrõ-ìśe, õrõ-àpèjúwe, õrõ-atökùn, õrõ-asopõOLÙKÖ:

Kô àpççrç àwôn õrõ tí ó wà lábë ìsõrí õrõ kõõkan. Bí àpççrç: 1. Õrõ-orúkô: ilé, igi, ojú, ayò, Akin, Adé.

 2. Õrõ-aröpò orúkô: mo, ó, a, mi, wa, wôn.

AKËKÕÖ:

 1. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí ìsõrí õrõ kõõkan

 2. Kô àwôn àpççrç tí olùkö kô sókè

d. pe àwôn õrõ náà bí olùkö śe pè é fún wôn

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 • Pátákó ìkõwé

 • Fídíò

 • Kádíböõdù

7.

ÌSÕRÍ ÕRÕ: Õrõ-Aröpò Orúkô

ÀKÓÓNÚ IŚË

Õrõ-aröpò orúkô

Õrõ-orúkô afarajorúkôOLÙKÖ:

a. Kô àwôn õrõ aröpò orúkô sílê bí i: a, mo, ç, wôn, yin, ìwô àti bëê bëê lô.

b. Kíkô õrõ aröpò orúkô afarajorúkô sílê, àwa, èmi, àwôn,êyin ati bëê bëê lô.

d. Kô ipò tí a ti lè lo ìkõõkan àpççrç ipò çni kìn-ín-ín çyô tàbí õpõ.AKËKÕÖ:

a. Ka àwôn õrõ aröpò orúkô àti ti afarajorúkô sílê.

b. Gbìyànjú láti mô ipò çnìkejì tàbí ìkëta çyô tàbí õpõ.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:


 • Pátákó ìkõwé

 • Kádíböõdù

8.

ÀWÔN ÊYÀ ARA FÚN ÌRÓ ÈDÈ PÍPÈ

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Kín ni àfipè?

b. Oríśi àfipè tí ó wà

d. Êyà ara àfipè àkànmölê àti àsúnsí

e. Êyà ara àfipè tí a lè fi ojú rí àti èyí tí a kò lè fojú rí.OLÙKÖ:

a. Mënuba àwôn êyà ara tí ó wà.

b. Sô ní sókí nípa êyà ara yòókù kí o sì śàlàyé lórí àwôn èyí tí à ń lò fún pípe ìró.

d. Pín àwôn êyà ara tí a fi ń pe ìró náà sí ìsõrí wôn gëgë bí i; àfipè àsúnsí àti àfipè àkànmölê.

e. Bákan náà ni olùkö yóò sô nípa àwôn àfipè tí a lè fojú rí àti èyí tí a kò lè fojú rí .

AKËKÕÖ:

a. Akëkõö yóò kô ohun tí olùkö kô sójú pátákó sílê

b. Yóò béèrè ìyàtõ tí ó wà nínú àfipè àsúnsí àti àkànmölê, àfipè tí a lè fi ojú rí àti èyí tí a kò le fojú rí.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:


 • Pátákó ìköwé

 • Kádíböõdù

 • Àwòrán ènìyàn tí ó fi àwôn ibi ìpè ìró hàn.

9.

ÌWÉ KÍKÀ

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Śíśe àtúpalê ìwé eré-onítàn

b. Wíwá àśà àti ìśe ilê Yorùbá jáde nínú ìwé náà.

d. Śíśe àfihàn àwôn ìlò èdè àti çwà èdè inú ìwé náà.
OLÙKÖ:

 1. Olùkö yóò jë kí àwôn akëkõö ka ìwé eré-onítàn

 2. Sô díê nínú ìlò èdè àti çwà èdè tí ó súyô

AKËKÕÖ:

a. Àwôn akëkõö yóò ní òye ohun tí ìtàn inú ìwé dálé.

b. Wôn yóò lè dá çwà èdè mõ

d. Wôn yóò sì lè töka sí àwôn àśà àti ìśe ilê Yorùbá.OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 • Pátákó ìkõwé

 • Ìwé eré-onítàn tí a yàn

10.

ÊSÌN ÒDE ÒNÍ

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Oríśiríśi êsìn tí a ní nílê Yorùbá – êsìn àbáláyé

b.Oríśiríśi êsìn òde òní bí i Kìrìsítíënì, Mùsùlùmí, Êkáńkà, Gúrúmàrajì, Búdà àti bëê bëê lô.

d. Õnà ìjösìn fún àwôn çlësìn.OLÙKÖ:

a. Sísô nípa êsìn àbáláyé

b. Àwôn òrìśà ilê Yorùbá àti bí a śe ń bô wön.

d. Àwôn oríśi êsìn tí a ní lóde òní.AKËKÕÖ:

a. Àdàkô ohun tí olùkö kô sójú pátákó.

b. Mô àwôn õnà tí çlësìn kõõkan ń gbà jösìn.

d. Béèrè ìbéèrè lórí ohun tí a kö.OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 • Pátákó ìkõwé

 • Àwòrán tí ó fi ìlànà êsìn kõõkan hàn.

11.

ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ

12.

ÌDÁNWÒ

Download 3.49 Mb.

Share with your friends:
1   ...   21   22   23   24   25   26   27   28   ...   47
The database is protected by copyright ©ininet.org 2023
send message

    Main page