Education resource centre


YORÙBÁ SS 2 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍDownload 3.25 Mb.
Page25/49
Date29.01.2017
Size3.25 Mb.
#11610
1   ...   21   22   23   24   25   26   27   28   ...   49

YORÙBÁ SS 2 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍ

ÕSÊ

ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ

ÀMÚŚE IŚË


1

ÈDÈ: Àròkô Aláríyànjiyàn

ÀKÓÓNÚ IŚË

 1. Kíkô àwôn ìlapa èrò àròkô aláríyànjiyàn

 2. Àròkô aláríyànjiyàn kíkô

OLÙKÖ:

a. Śe àlàyé ìgbésê inú ìlapa èrò àkôlé àròkô aláríyànjiyàn kan ní kíkún.

b. Tö akëkõö sönà láti lo ìlapa èrò yçn láti kô àròkô.

d. Yç iśë akëkõö wò

e. Darí akëkõö láti śe àríyànjiyàn lórí orí-õrõ tí wön yàn ní kíláásì.

AKËKÕÖ:

a. Tëtí sí àlàyé olùkö kí o sì kíyèsí àwôn ìgbésê ìlapa èrò tí olùkö kô sílê.

b. Kô àwôn àlàyé ojú pátákó sílê.

d. Lo ìlapa èrò tí olùkö śe láti kô àròkô.

e. Kópa nínú śíśe àríyànjiyàn lórí orí-õrõ ní kíláásì.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:


 • Ìwé tí ó ní ìlapa èrò nínú àti àpççrç àròkô aláriiyànjiyàn.

2.

LÍTÍRÈŚÕ: Àtúpalê Ìwé Eré-Onítàn

ÀKÓÓNÚ IŚË

 1. Kókó õrõ

 2. Ìfìwàwêdá

d. Àhunpõ ìtàn

e. Ibùdó ìtàn

ç. Êdá ìtàn

f. Ìlò-èdè

g. Ìjçyô àśà

gb. Àmúyç àti àléébùOLÙKÖ:

a. Tö akëkõö sönà láti kà ìwé eré-onítàn.

b. Śe àlàyé ní kíkún lórí ìjçyô atótónu iśë nínú ìwé eré-onítàn:


 • kókó õrõ

 • Ìfìwàwêdá

 • Àhunpõ ìtàn

 • Ibùdó ìtàn

 • Êdá ìtàn

 • Ìlò èdè

 • Ìjçyô àśà

 • Àmúyç àti àléébù

d. Kíkô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì tó súyô sí ojú pátákó kí o sì śàlàyé ìtumõ wôn.

AKËKÕÖ:

a. Ka ìwé eré-onítàn wá láti ilé àti nínú kíláásì.

b. Tëtí sí àlàyé olùkö

d. Kô àwôn õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó ìwéOHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 • Ìwé eré-oníśe

3.

ÀŚÀ: Ìsìnkú

ÀKÓÓNÚ IŚË

 1. oríśiríśi bí ikú ti ń pani: àìsàn, ìjàýbá lóríśiríśi, ikú àìtöjö, fífôwö-rôrí-kú

 2. Ìtúfõ

d. Ìtöjú òkú

e. Títë òkú ní ìtë êyç

ç. Ìbánikëdùn

f. Bí a śe ń sin òkú ní ayé àtijö

g. Ìsìnkú abàmì êdá; abuké, çni ti odò gbé, çni tó pokùnso, çni tó jábö lórí õpç.

gb. Òkú ríró

h. Śíśe eegun òkú/ àgõ fífà abbl


OLÙKÖ:

a. Śe àlàyé kíkún nípa oríśiríśi ikú tí ń pani

b. Śe àlàyé bí a ti ń sin oríśiríśi òkú àti ètùtù tí ó rõ mö ôn.

d. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì sí ojú pátákó ìkõwé.

e. Śe àlàyé kíkún lórí ìsìnkú àgbà.

AKËKÕÖ:

a. Tëtí sí àwôn àlàyé olùkö.

b. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì tí olùkö kô sojú pátákó ìkõwé sínú ìwé rê

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:


 • Pátákó

 • Rédíò

 • Ìwé kíkà lórí ewì alohùn tó jçmö ìsìnkú

 • Oríśiríśi àwòrán tí ó jçmö ìsìnkú.

4.

ÈDÈ: Gbólóhùn

ÀKÓÓNÚ IŚË

 1. Oríkì gbólóhùn

 2. Àlàyé ìpín gbólóhùn nípa ìhun

d. Alábödé

e. Oníbõ


ç. Alákànpõ

OLÙKÖ:

a. Kô oríśiríśi àpççrç gbólóhùn sí ojú pátákó ìkõwé.

b. Sô fún akëkõö láti fa ìlà sí abë õrõ-ìśe àti olùwà nínú gbólóhùn

d. Śe àlàyé àbùdá gbólóhùn alábödé, oníbõ àti alákànpõ.AKËKÕÖ:

a. Tëtí sí àlàyé olùkö

b. Śe àwòkô àwôn àpççrç gbólóhùn tí olùkö kô sójú pátákó.

d. Fa ìlà sí abë õrõ-iśë àti olùwà rê.OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 • Pátákó ìkõwé

5.

ÀŚÀ: Eré Ìdárayá

ÀKÓÓNÚ IŚË

 1. Oríśiríśi eré ìdárayá

 2. Eré òśùpá bí i – bojúbojú, sa-n-sálùbö

d. Eré abëlé

e. Eré ìta gbangba bí i; òkòtó, àrìn, ìjàkadì/ çkç, ògò gbígbõn abbl.OLÙKÖ:

a. Śe àlàyé bí a ti ń śe díê nínú eré ìdárayá tí ó mënuba.

b. Tö àwôn akëkõö sönà láti śe àwôn eré ìdárayá.

d. Kô àwôn orin inú eré ìdárayá náà sójú pátákóAKËKÕÖ:

a. Sô ohun tí o mõ nípa eré ìdárayá sáájú ìdánilëkõö.

b. Dárúkô díê nínú eré ìdárayá mìíràn tí o mõ.

d. Tëtí sí àlàyé olùkö.

e. Kópa nínú eré ìdárayá tí olùkö kô sójú pátákó.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:


 • Ôpön ayò

 • Ômô ayò

 • Òkòtó

 • Àrìn abbl

6.

LÍTÍRÈŚÕ: Àtúpalê Ewì Alohùn (Àsàyàn ìwé kan)

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Àkóónú  • Kókó õrõ, àśà tó súyô

  • Ìhun

  • Lílé/ gbígbè, àdákô, àjùmõkô abbl

  • Ìlò èdè: ônà èdè àti ìsôwölo-èdè

  • Ìjçyô àśà

b. Lítírèśõ alohùn mìíràn

d. Õgangan ipò àwôn akéwì, êsìn/ ìśe wôn, àkókò ìkéwì abbl
OLÙKÖ:

a. Jë kí àwôn akëkõö gbìyànjú láti ka ewì alohùn löpõlôpõ ìgbà.

b. Śe àlàyé lórí kókó õrõ, êkö, ìlò-èdè àmúyç àti àléébù inú ìwé àsàyàn ewì alohùn.

AKËKÕÖ:

a. Fi etí sí ewì tí olùkö ń kà fún wôn.

b. Gbìyànjú láti kéwì tí o bá mõ.

d. Ka ìwé àsàyàn yìí.OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 • Ìwé tó jçmö ewì alohùn

 • Àwòrán tó bá ewì yìí mu.

 • Pátákó ìkõwé

 • Téèpù

7.

ÀŚÀ: Ètò Ìśèlú

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Ààtò agbo ilé  • Iśë baálé ilé

  • Iśë ìyálé ilé

  • Iśë obìnrin ilé

  • Iśë ômô ilé

  • Ètò oyè jíjç

  • Oyè ìdílé

  • Oyè ìfidánilölá

  • Oyè êsìn

  • Oyè ògbóni

  • Oyè ológun

OLÙKÖ:

a. Śe àlàyé lórí ààtò agbo-ilé àti ààtò oyè jíjç.

b. Śe ètò eré-oníśe lórí àśà ìfinijoyè

d. Fi fídíò ayçyç ìfinijoyè han àwôn akëkõöAKËKÕÖ:

a. Tëtí sí àlàyé olùkö

b. Kópa nínú eré-oníśe lórí àśà ìfinijoyè

d. Wo fídíò ìfôbajçOHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 • Àwòrán

 • Fídíò ayçyç ìfinijoyè, ìdájö ní köõtù ìbílê abbl.

8.

ÈDÈ: Àròkô Oníròyìn

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Àròkô oníròyìn 1. Ìròyìn jàýbá ôkõ kan tó sojú mi pàtó

 2. Ìròyìn eré böõlù tí ó sojú mi

 3. Ìrìn-àjò ojúmitó sí Àgö ôlöpàá

OLÙKÖ:

  1. Śe àlàyé ìgbésê àròkô

  2. Śe àlàyé ìfáàrà

d. Śe àlàyé ìpín afõ

e. Śe àlàyé ìfàmìsí

ç. Śe àlàyé ìgúnlê

f. Śe àlàyé ìlò èdèAKËKÕÖ:

 1. Ka àròkô oníròyìn tí ó pegedé

 2. Kô àròkô oníròyìn nípa títêlé ìgbésê tí olùkö ti śàlàyé rê

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

  • Ìwé àpilêkô lórí àròkô

  • Ìwé iśë àti pátákó ìkõwé

9.

ÀŚÀ: Ètò Ôrõ-Ajé (Ìpolówó Ôjà)

a. Ìdí tí a fi ń polówó ôjà

b. Bí a śe ń polówó ôjà, b.a êkô tútù, ç ç jçran êkô

d. Ôgbön ìpolówó ôjà ní ayé àtijö àti òde òní, b.a ìpolówó lórí rédíò, tçlifísàn, ìwé ìròyìn, ìkiri abblOLÙKÖ

a. Tç ìpolówó ôjà tí a ti tê sórí téèpù fún àwôn akëkõö gbö.

b. Fún àwôn akëkõö ní àýfààní láti śe ìpolówó ôjà ní kíláásì.

d. Kó akëkõö lô śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ.AKËKÕÖ

a. Tëtí sí téèpù tí olùkö tê

b. Kópa nínú śíśe ìpolówó ôjà nínú kíláásì

d. Śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ láti gbö oríśiríśi ìpolówó ôjà.OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

 • Àtç

 • Fídíò

 • Rédíò

 • Êrô agbõrõ sílê

 • Téèpù

 • Tçlifísàn

 • Ìpolówó ôjà lóríśiríśi nínú ìwé ìròyìn abbl.

10.

LÍTÍRÈŚÕ: Itêsíwájú Àtúpalê Ewì Àpilêkô

 1. kókó õrõ

 2. Àśà àti ìśe tó súyô nínú ìwé náà

d. Ètò/ Ìhun

e. Ìlò èdè

ç. Àmúyç àti Àléébù


OLÙKÖ

a. jë kí akëkõö ka ewì àpilêkô

b. śe àlàyé ní kíkún lórí ìjçyô àkóónú

d. kô bí ó śe jçyô nínú ewì àpilêkô àsàyàn: • kókó õrõ

 • ìhun (ètò)

 • ìlò èdè

 • àmúyç àti àléébù

d. Kô àwôn õrõ tí ó śe pàtàkì pàtàkì sí ojú pátákó ìkõwé, śíśe àlàyé lórí ìtumõ wôn.

AKËKÕÖ

 1. Ka àsàyàn ewì ní àkàsínú àti àkàsíta

 2. Tëtí sí àlàyé olùkö

d. Da àwôn õrõ tí olùkö kô sójú pátákó kô sínú ìwé.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

 • Àsàyàn ìwé ewì àpilêkô

 • Àwòrán tó bá ewì kõõkan mu.

11.

ÈDÈ: Õrõ Àyálò

a. Àlàyé lórí õrõ àyálò

b. Òfin tí ó de õrõ àyálò

d. Okùnfà õrõ àyálò–Êsìn, Ètò ôrõ-ajé àti bëê bëê lô.

e. Ìlànà õrõ àyálò (àfojúyá àti àfetíyá)


OLÙKÖ

a. Śe àlàyé kíkún lórí õrõ àyálò

b. Śe àlàyé okùnfa õrõ àyálò

d. Śe àlàyé fún àwôn akëkõö lórí ìlànà õrõ àyálò àfojúyá àti àfetíyá.AKËKÕÖ

a. Tëtí sí àlàyé olùkö

b. kô kókó ìdánilëkõö sílê.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI


 • Pátákó ìkõwé

 • Kádíböõdù tí ó śe àfihàn õrõ àyálò tí a yá wô inú èdè Yorùbá.

12.

ÈDÈ: Õrõ àgbàsô (Afõ asafõ àti afõ Agbàrán)

a. Ìtumõ õrõ àgbàsô

b. Àlàyé lórí afõ asafõ àti afõ agbàrán

d. Àwôn atöka õrõ àgbàsô.

e. Àwôn ìsõrí õrõ tí ó máa jçyô nínú õrõ àgbàsô.


OLÙKÖ

a. Śe àlàyé ìtumõ õrõ àgbàsô fún àwôn akëkõö.

b. Jë kí akëkõö mô ìyàtõ láàrin afõ asafõ àti afõ agbàrán.

d. Kô àwôn atöka àgbàsô fún akëkõö

e. Kô àwôn ìsõrí õrõ tí ó máa ń jçyô nínú õrõ àgbàsô sí ojú pátákó ìkôwé.

AKËKÕÖ

a. Tëtí sí àlàyé olùkö.

b. Kí akëkõö śe àgbàsô õrõ láàrin ara wôn.

d. Kô àwôn õrõ tí ó śe pàtàkì tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé.OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

 • Pátákó ìkõwé

 • Kádíböõdù tí ó śe àfihàn õrõ atöka õrõ àgbàsô.

13.


ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ
14.

ÌDÁNWÒ
YORÙBÁ SS 2 TÁÀMÙ KEJÌ

ÕSÊ

ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ

ÀMÚŚE IŚË


1.

ÈDÈ: Àròkô (Lëtà gbêfê)

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Àdírësì

b. Ìkíni

d. Àkôlé


e. Déètì

ç. Kókó õrõ

f. Àsôkágbá


OLÙKÖ:

a. Tö akëkõö sõnà láti kô àròkô

b. Gbìyànjú láti kô àròkô tí olùkö bá yàn fún wôn

AKËKÕÖ:

a. Têlé ìlànà olùkö láti kô àròkô.

b. Gbìyànjú láti kô àròkô tí olùkö bá yàn fún wôn

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:


 • Ìwé àpilêkô lórí àròkô

 • Àpççrç lëtà gbêfê tó múná dóko

 • pátákó ìkõwé

2.

ÌWÉ KÍKA: Àtúpalê Ìtàn Àròsô

ÀKÓÓNÚ IŚË

Akëkõö yóò le śe àtúpalê

a. Kókó õrõ

b. Àhunpõ ìtàn àti ìfìwàwêdá

d. Ibùdó ìtàn

e. Ôgbön ìsõtàn

ç. Ìlo èdè

f. Àśà tó jçyô nínú ìtàn àròsôOLÙKÖ:

a. Jë kí akëkõö ka ìwé ìtàn àròsô ní àkàyé

b. Śe àlàyé tó kún lórí ìwé ìtàn àròsô

d. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì tí ó jçyô jáde sójú pátákóAKËKÕÖ:

a. Ka ìwé ìtàn àròsô wa láti ilé àti nínú kíláásì

b. Tëtí sí àlàyé olùkö

d. Da àwôn õrõ tí olùkö kô sójú pátákó kô sínú ìwé rç.OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 • Fídíò

 • Téèpù

 • Tçlifísàn

 • Êrô agbõrõ sô

3.

ÈDÈ: Aáyan Ògbufõ

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Títúmõ àyôlò ewì ní èdè Gêësì kan sí èdè Yorùbá

b. Títúmõ ewì ní èdè Yorùbá sí èdè Gêësì.


OLÙKÖ:

a. Tö akëkõö sönà láti túmõ ewì kúkurú kan ní èdè geeai sí Yorùbá.

b. Tö akëkõö sönà láti túmõ ewì Yorùbá sí èdè Gêësì.

AKËKÕÖ:

a. Túmõ àyôlò ewì kúkurú kan ní èdè Gêësì àti Yorùbá

b. Túmõ ewì kúkurú ní èdè Yorùbá sí èdè Gêësì

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI


 • Ìwé ewì àpilêkô ní èdè Gêësì àti Yorùbá.

 • pátákó ìkõwé

 • ìwé atúmõ èdè

4.

ÈDÈ: Ìhun Gbólóhùn – oríśiríśi awë gbólóhùn

a. Ìhun awë-gbolohun

b. Iśë tí awë-gbólóhùn ń śe nínú gbólóhùn


OLÙKÖ:

a. Śe àlàyé ìyàtõ láàrin àpólà àti awë-gbólóhùn.

b. Śe àlàyé àbùdá awë-gbólóhùn.

d. Śe àlàyé olórí awë-gbólóhùn

e. Śe àlàyé awë-gbólóhùn afarahç

ç. Fi ìyàtõ han láàrin olórí gbólóhùn àti awë-gbólóhùn afarahç.AKËKÕÖ:

a. Fi àpólà gbólóhùn wé awë-gbólóhùn láti le mô ìyàtõ tó wà láàrin wôn.

b. Sô àbùdá awë-gbólóhùn afarahç

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:


 • Pátákó ìkõwé

 • Kádíböõdù tí ó ní àkôsílê àpólà õrõ-orúkô, àpólà-atökùn, olórí awë-gbólóhùn àti awë-gbólóhùn afarahç

5.

ÀŚÀ: Ètò Ogún jíjç

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Ìtumõ ogún àti ohun tí à ń jç lógún

b. Ìyàtõ láàrin ogún ìyá àti ogún baba

d. Õnà tí à ń gbà pín ogún

e. Àwôn tó ní êtö sí ogún

ç. Wàhálà tí ó rõ mö ogún pínpínOLÙKÖ:

a. Śe àlàyé ohun tí ogún jíjç jë fún àwôn akëkõö.

b. Tö àwôn akëkõö sönà láti śe eré oníśe lórí ètò ogún pínpín nínú kíláásì.

d. Śe àlàyé ìyàtõ ogún ìyá àti ogún baba

e. Jë kí akëkõö wo/ tëtí sí ètò ogún pínpín lórí ètò ìyanjú aáwõ lórí tçlifísàn àti rédíò.

AKËKÕÖ:

a. Tëtí sí àlàyé olùkö

b. Kópa nínú eré ètò ogún pínpín nínú kíláásì

d. Wo ètò ogún pínpín ní kóòtùOHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:

 • Àwòrán ohun tí à ń jogún; ilé, ilê, aśô abbl

 • Fídíò tí ó fi ibi tí a ti ń pín ogún hàn.

6.

ÈDÈ: Pípajç àti ìsúnkì

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Oríkì ìpajç

b. Òfin ìpajç

d. Fáwëlì pípajç

e. Köńsónáýtì pípajç

ç. Ìyöpõ fáwëlì

f. Oríkì ìsúnkì

g. ìbáśepõ tí ó wà láàrin ìpajç àti ìsúnkìOLÙKÖ:

a. Sô oríkì ìpajç àti ìsúnkì àti ìjçyôpõ

b. Sô òfin tó de ìpajç, ìsúnkì àti ìyöpõ fáwëlì

d. Sô oríśiríśi ìpajç tí ó wà

e. Béèrè ìbéèrè löwö akëkõö

ç. Dáhùn ìbéèrè àwôn akëkõö

f. Yan kókó sójú pátákó

AKËKÕÖ:

a. Tëtí sí olùkö.

b. Béèrè ìbéèrè löwö olùkö

d. Dáhùn ìbéèrè olùkö

e. Śe àkôsílê sínú ìwé rç.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI


 • Pátákó ìkõwé

7.

LÍTÍRÈŚÕ: Ìtêsíwájú Àtúpalê Ewì Alohùn

ÀKÓÓNÚ IŚË

 1. kókó õrõ

 2. Êsìn/ ìśe tí ewì rõ mö

d. Ìlù, ijó, orin tí ó jç mö ewì

e. Ìjçyô àśà àti ìśe

ç. Ìlò èdè

f. Àmúyç àti àléébù nínú ewì náàOLÙKÖ:

a. Śe àlàyé àwôn kókó õrõ inú ewì náà

b. Śe àlàyé ààtò

d. Śe àlàyé ônà èdè àti ìsôwö-lo-èdè tó jçyô

e. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì tí ó súyô sí ojú pátákó

AKËKÕÖ:

a. Fi ara balê ka àsàyàn ìwé ewì alohùn

b. Śe àkôsílê àwôn kókó õrõ śíśê-n-têlé

d. Töka sí ônà èdè àti ìsôwö-lo-èdè

e. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì ojú pátákó ìkõwé sílê

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:


 • Àsàyàn ìwé ewì alohùn

 • Àwòrán ohun tí ewì alohùn dálé

 • Êrô agbõrõsílê àti téèpù

8.

ÀŚÀ: Ètò Ìdájö

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Õnà tí a fi ń śe ìdájö látijö ni õdõ; baálê, ìjòyè ìlú, ôba. Ipa çmçsê/ ìlàrí

b. Ìdájö lóde òní: ilé çjö ìbílê, ilé çjö gíga, ilé çjö kò-të-mi-lörùn, ilé çjö tó ga jù. Ìgbìmõ elétíigbáròyé, ipa aködà, ôlöpàá, wödà abbl.


OLÙKÖ:

a. Śe àlàyé ètò ìdájö látijö àti lóde oni

b. Śe àlàyé ewu tó wà nínú dídájö èké àti àýfààní ìdájö òdodo

AKËKÕÖ

a. Sô ohun tí o mõ nípa ètò ìdájö

b. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí ètò ìdájö

d. Béèrè ìbéèrè tí ó bá rú ô lójúOHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

 • Àwòrán tí ó fi ètò ìdájö hàn

 • Fíìmù àti fídíò ibi tí wôn ti ń fi ìdájö hàn.

9.

ÈDÈ: Àrànmö

ÀKÓÓNÚ IŚË

 1. Oríkì àrànmö

 2. Àrànmö ohùn

d. Àrànmö Fáwëlì

e. Àrànmö iwájú

ç. Àrànmö êyìn

f. Àrànmö aláìfòró àti àrànmö afòróOLÙKÖ

a. Śe àlàyé fún àwôn akëkõö ohun tí àrànmö jë

b. Sô oríśiríśi àrànmö tí ó wà pêlú àpççrç tí ó múná dóko

d. Béèrè ìbéèrè löwö akëkõö

e. Śe àkôsílê sójú pátákó

AKËKÕÖ

a. Tëtí sí olùkö

b. Béèrè ìbéèrè löwö olùkö

d. Dáhùn ìbéèrè olùkö

e. Śe àkôsílê sínú ìwé rç

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI


 • Pátákó ìkõwé

10.

ÈDÈ: Wúnrên onítumõ gírámà

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. oríkì wúnrên onítumõ àdámö

b. Ibá-ìśêlê ôjö iwájú

d. Ibá-ìśêlê löwölöwö

e. Ibá-ìśêlê atërçrç

ç. Ibá-ìśêlê aśetán

f. Ibá-ìśêlê bárakú


OLÙKÖ

a. Olùkö yóò śàlàyé fún akëkõö ohun tí à ń pè ní wúnrên onítumõ gírámà.

b. Olùkö yóò kô àwôn wúnrên yìí sílê: yóò, máa, ti, ń, àti bëê bëê lô

d. Olùkö yóò kö àwôn akëkõö ní ibá yìí; ôjö iwájú, löwölöwö, aśetán, atërçrç àti bárakú.AKËKÕÖ

a. Akëkõö yóò tëtí sí olùkö

b. Akëkõö yóò dáhùn ìbéèrè

d. Akëkõö yóò kô àkôsílê sínú ìwé rêOHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

 • Pátákó ìkõwé

 • Kádíböõdù tí olùkö ti kô àwôn õrõ tí ó śàfihàn àwôn ibá yìí nínú gbólóhùn láti ilé.

11.

ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ
12.

ÌDÁNWÒ

Download 3.25 Mb.

Share with your friends:
1   ...   21   22   23   24   25   26   27   28   ...   49
The database is protected by copyright ©ininet.org 2024
send message

    Main page