ÕSÊ
|
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
|
ÀMÚŚE IŚË
|
1
|
ÈDÈ: Àròkô Aláríyànjiyàn
ÀKÓÓNÚ IŚË
-
Kíkô àwôn ìlapa èrò àròkô aláríyànjiyàn
-
Àròkô aláríyànjiyàn kíkô
|
OLÙKÖ:
a. Śe àlàyé ìgbésê inú ìlapa èrò àkôlé àròkô aláríyànjiyàn kan ní kíkún.
b. Tö akëkõö sönà láti lo ìlapa èrò yçn láti kô àròkô.
d. Yç iśë akëkõö wò
e. Darí akëkõö láti śe àríyànjiyàn lórí orí-õrõ tí wön yàn ní kíláásì.
AKËKÕÖ:
a. Tëtí sí àlàyé olùkö kí o sì kíyèsí àwôn ìgbésê ìlapa èrò tí olùkö kô sílê.
b. Kô àwôn àlàyé ojú pátákó sílê.
d. Lo ìlapa èrò tí olùkö śe láti kô àròkô.
e. Kópa nínú śíśe àríyànjiyàn lórí orí-õrõ ní kíláásì.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
-
Ìwé tí ó ní ìlapa èrò nínú àti àpççrç àròkô aláriiyànjiyàn.
|
2.
|
LÍTÍRÈŚÕ: Àtúpalê Ìwé Eré-Onítàn
ÀKÓÓNÚ IŚË
-
Kókó õrõ
-
Ìfìwàwêdá
d. Àhunpõ ìtàn
e. Ibùdó ìtàn
ç. Êdá ìtàn
f. Ìlò-èdè
g. Ìjçyô àśà
gb. Àmúyç àti àléébù
|
OLÙKÖ:
a. Tö akëkõö sönà láti kà ìwé eré-onítàn.
b. Śe àlàyé ní kíkún lórí ìjçyô atótónu iśë nínú ìwé eré-onítàn:
-
kókó õrõ
-
Ìfìwàwêdá
-
Àhunpõ ìtàn
-
Ibùdó ìtàn
-
Êdá ìtàn
-
Ìlò èdè
-
Ìjçyô àśà
-
Àmúyç àti àléébù
d. Kíkô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì tó súyô sí ojú pátákó kí o sì śàlàyé ìtumõ wôn.
AKËKÕÖ:
a. Ka ìwé eré-onítàn wá láti ilé àti nínú kíláásì.
b. Tëtí sí àlàyé olùkö
d. Kô àwôn õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó ìwé
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
|
3.
|
ÀŚÀ: Ìsìnkú
ÀKÓÓNÚ IŚË
-
oríśiríśi bí ikú ti ń pani: àìsàn, ìjàýbá lóríśiríśi, ikú àìtöjö, fífôwö-rôrí-kú
-
Ìtúfõ
d. Ìtöjú òkú
e. Títë òkú ní ìtë êyç
ç. Ìbánikëdùn
f. Bí a śe ń sin òkú ní ayé àtijö
g. Ìsìnkú abàmì êdá; abuké, çni ti odò gbé, çni tó pokùnso, çni tó jábö lórí õpç.
gb. Òkú ríró
h. Śíśe eegun òkú/ àgõ fífà abbl
|
OLÙKÖ:
a. Śe àlàyé kíkún nípa oríśiríśi ikú tí ń pani
b. Śe àlàyé bí a ti ń sin oríśiríśi òkú àti ètùtù tí ó rõ mö ôn.
d. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì sí ojú pátákó ìkõwé.
e. Śe àlàyé kíkún lórí ìsìnkú àgbà.
AKËKÕÖ:
a. Tëtí sí àwôn àlàyé olùkö.
b. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì tí olùkö kô sojú pátákó ìkõwé sínú ìwé rê
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
-
Pátákó
-
Rédíò
-
Ìwé kíkà lórí ewì alohùn tó jçmö ìsìnkú
-
Oríśiríśi àwòrán tí ó jçmö ìsìnkú.
|
4.
|
ÈDÈ: Gbólóhùn
ÀKÓÓNÚ IŚË
-
Oríkì gbólóhùn
-
Àlàyé ìpín gbólóhùn nípa ìhun
d. Alábödé
e. Oníbõ
ç. Alákànpõ
|
OLÙKÖ:
a. Kô oríśiríśi àpççrç gbólóhùn sí ojú pátákó ìkõwé.
b. Sô fún akëkõö láti fa ìlà sí abë õrõ-ìśe àti olùwà nínú gbólóhùn
d. Śe àlàyé àbùdá gbólóhùn alábödé, oníbõ àti alákànpõ.
AKËKÕÖ:
a. Tëtí sí àlàyé olùkö
b. Śe àwòkô àwôn àpççrç gbólóhùn tí olùkö kô sójú pátákó.
d. Fa ìlà sí abë õrõ-iśë àti olùwà rê.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
|
5.
|
ÀŚÀ: Eré Ìdárayá
ÀKÓÓNÚ IŚË
-
Oríśiríśi eré ìdárayá
-
Eré òśùpá bí i – bojúbojú, sa-n-sálùbö
d. Eré abëlé
e. Eré ìta gbangba bí i; òkòtó, àrìn, ìjàkadì/ çkç, ògò gbígbõn abbl.
|
OLÙKÖ:
a. Śe àlàyé bí a ti ń śe díê nínú eré ìdárayá tí ó mënuba.
b. Tö àwôn akëkõö sönà láti śe àwôn eré ìdárayá.
d. Kô àwôn orin inú eré ìdárayá náà sójú pátákó
AKËKÕÖ:
a. Sô ohun tí o mõ nípa eré ìdárayá sáájú ìdánilëkõö.
b. Dárúkô díê nínú eré ìdárayá mìíràn tí o mõ.
d. Tëtí sí àlàyé olùkö.
e. Kópa nínú eré ìdárayá tí olùkö kô sójú pátákó.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
-
Ôpön ayò
-
Ômô ayò
-
Òkòtó
-
Àrìn abbl
|
6.
|
LÍTÍRÈŚÕ: Àtúpalê Ewì Alohùn (Àsàyàn ìwé kan)
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. Àkóónú
-
Kókó õrõ, àśà tó súyô
-
Ìhun
-
Lílé/ gbígbè, àdákô, àjùmõkô abbl
-
Ìlò èdè: ônà èdè àti ìsôwölo-èdè
-
Ìjçyô àśà
b. Lítírèśõ alohùn mìíràn
d. Õgangan ipò àwôn akéwì, êsìn/ ìśe wôn, àkókò ìkéwì abbl
|
OLÙKÖ:
a. Jë kí àwôn akëkõö gbìyànjú láti ka ewì alohùn löpõlôpõ ìgbà.
b. Śe àlàyé lórí kókó õrõ, êkö, ìlò-èdè àmúyç àti àléébù inú ìwé àsàyàn ewì alohùn.
AKËKÕÖ:
a. Fi etí sí ewì tí olùkö ń kà fún wôn.
b. Gbìyànjú láti kéwì tí o bá mõ.
d. Ka ìwé àsàyàn yìí.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
-
Ìwé tó jçmö ewì alohùn
-
Àwòrán tó bá ewì yìí mu.
-
Pátákó ìkõwé
-
Téèpù
|
7.
|
ÀŚÀ: Ètò Ìśèlú
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. Ààtò agbo ilé
-
Iśë baálé ilé
-
Iśë ìyálé ilé
-
Iśë obìnrin ilé
-
Iśë ômô ilé
-
Ètò oyè jíjç
-
Oyè ìdílé
-
Oyè ìfidánilölá
-
Oyè êsìn
-
Oyè ògbóni
-
Oyè ológun
|
OLÙKÖ:
a. Śe àlàyé lórí ààtò agbo-ilé àti ààtò oyè jíjç.
b. Śe ètò eré-oníśe lórí àśà ìfinijoyè
d. Fi fídíò ayçyç ìfinijoyè han àwôn akëkõö
AKËKÕÖ:
a. Tëtí sí àlàyé olùkö
b. Kópa nínú eré-oníśe lórí àśà ìfinijoyè
d. Wo fídíò ìfôbajç
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
-
Àwòrán
-
Fídíò ayçyç ìfinijoyè, ìdájö ní köõtù ìbílê abbl.
|
8.
|
ÈDÈ: Àròkô Oníròyìn
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. Àròkô oníròyìn
-
Ìròyìn jàýbá ôkõ kan tó sojú mi pàtó
-
Ìròyìn eré böõlù tí ó sojú mi
-
Ìrìn-àjò ojúmitó sí Àgö ôlöpàá
|
OLÙKÖ:
-
Śe àlàyé ìgbésê àròkô
-
Śe àlàyé ìfáàrà
d. Śe àlàyé ìpín afõ
e. Śe àlàyé ìfàmìsí
ç. Śe àlàyé ìgúnlê
f. Śe àlàyé ìlò èdè
AKËKÕÖ:
-
Ka àròkô oníròyìn tí ó pegedé
-
Kô àròkô oníròyìn nípa títêlé ìgbésê tí olùkö ti śàlàyé rê
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
-
Ìwé àpilêkô lórí àròkô
-
Ìwé iśë àti pátákó ìkõwé
|
9.
|
ÀŚÀ: Ètò Ôrõ-Ajé (Ìpolówó Ôjà)
a. Ìdí tí a fi ń polówó ôjà
b. Bí a śe ń polówó ôjà, b.a êkô tútù, ç ç jçran êkô
d. Ôgbön ìpolówó ôjà ní ayé àtijö àti òde òní, b.a ìpolówó lórí rédíò, tçlifísàn, ìwé ìròyìn, ìkiri abbl
|
OLÙKÖ
a. Tç ìpolówó ôjà tí a ti tê sórí téèpù fún àwôn akëkõö gbö.
b. Fún àwôn akëkõö ní àýfààní láti śe ìpolówó ôjà ní kíláásì.
d. Kó akëkõö lô śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ.
AKËKÕÖ
a. Tëtí sí téèpù tí olùkö tê
b. Kópa nínú śíśe ìpolówó ôjà nínú kíláásì
d. Śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ láti gbö oríśiríśi ìpolówó ôjà.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
-
Àtç
-
Fídíò
-
Rédíò
-
Êrô agbõrõ sílê
-
Téèpù
-
Tçlifísàn
-
Ìpolówó ôjà lóríśiríśi nínú ìwé ìròyìn abbl.
|
10.
|
LÍTÍRÈŚÕ: Itêsíwájú Àtúpalê Ewì Àpilêkô
-
kókó õrõ
-
Àśà àti ìśe tó súyô nínú ìwé náà
d. Ètò/ Ìhun
e. Ìlò èdè
ç. Àmúyç àti Àléébù
|
OLÙKÖ
a. jë kí akëkõö ka ewì àpilêkô
b. śe àlàyé ní kíkún lórí ìjçyô àkóónú
d. kô bí ó śe jçyô nínú ewì àpilêkô àsàyàn:
-
kókó õrõ
-
ìhun (ètò)
-
ìlò èdè
-
àmúyç àti àléébù
d. Kô àwôn õrõ tí ó śe pàtàkì pàtàkì sí ojú pátákó ìkõwé, śíśe àlàyé lórí ìtumõ wôn.
AKËKÕÖ
-
Ka àsàyàn ewì ní àkàsínú àti àkàsíta
-
Tëtí sí àlàyé olùkö
d. Da àwôn õrõ tí olùkö kô sójú pátákó kô sínú ìwé.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
-
Àsàyàn ìwé ewì àpilêkô
-
Àwòrán tó bá ewì kõõkan mu.
|
11.
|
ÈDÈ: Õrõ Àyálò
a. Àlàyé lórí õrõ àyálò
b. Òfin tí ó de õrõ àyálò
d. Okùnfà õrõ àyálò–Êsìn, Ètò ôrõ-ajé àti bëê bëê lô.
e. Ìlànà õrõ àyálò (àfojúyá àti àfetíyá)
|
OLÙKÖ
a. Śe àlàyé kíkún lórí õrõ àyálò
b. Śe àlàyé okùnfa õrõ àyálò
d. Śe àlàyé fún àwôn akëkõö lórí ìlànà õrõ àyálò àfojúyá àti àfetíyá.
AKËKÕÖ
a. Tëtí sí àlàyé olùkö
b. kô kókó ìdánilëkõö sílê.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
-
Pátákó ìkõwé
-
Kádíböõdù tí ó śe àfihàn õrõ àyálò tí a yá wô inú èdè Yorùbá.
|
12.
|
ÈDÈ: Õrõ àgbàsô (Afõ asafõ àti afõ Agbàrán)
a. Ìtumõ õrõ àgbàsô
b. Àlàyé lórí afõ asafõ àti afõ agbàrán
d. Àwôn atöka õrõ àgbàsô.
e. Àwôn ìsõrí õrõ tí ó máa jçyô nínú õrõ àgbàsô.
|
OLÙKÖ
a. Śe àlàyé ìtumõ õrõ àgbàsô fún àwôn akëkõö.
b. Jë kí akëkõö mô ìyàtõ láàrin afõ asafõ àti afõ agbàrán.
d. Kô àwôn atöka àgbàsô fún akëkõö
e. Kô àwôn ìsõrí õrõ tí ó máa ń jçyô nínú õrõ àgbàsô sí ojú pátákó ìkôwé.
AKËKÕÖ
a. Tëtí sí àlàyé olùkö.
b. Kí akëkõö śe àgbàsô õrõ láàrin ara wôn.
d. Kô àwôn õrõ tí ó śe pàtàkì tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
-
Pátákó ìkõwé
-
Kádíböõdù tí ó śe àfihàn õrõ atöka õrõ àgbàsô.
|
13.
|
ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ
|
|
14.
|
ÌDÁNWÒ
|
|