Education resource centre


YORÙBÁ SS 3 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍ



Download 2.23 Mb.
Page13/26
Date09.06.2018
Size2.23 Mb.
#53408
1   ...   9   10   11   12   13   14   15   16   ...   26

YORÙBÁ SS 3 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍ

ÕSÊ

ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ

ÀMÚŚE IŚË


1.

ÀŚÀ: Ìwà Ômôlúàbí

ÀKÓÓNÚ IŚË

Òtítö sísô, níní sùúrù, ìkíni, ìbõwõ fágbà, śíśe ojúśe nínú ilé, ìwàpêlë, ìgböràn àti bëê bëê lô.



OLÙKÖ

a. Sô irú çni tí à ń pè ní ômôlúàbí

b. Sô èrè tó wà nínú jíjë ômôlúàbí láwùjô

d. Lo òwe, orin, ewì, àśàyàn õrõ àti ìtàn láti fi kö akëkõö nípa adùn tó wà nínú ìwà rere

e. Sô ìśòro tí ômôlúàbí lè dojúkô àti bí ó śe lè borí wôn.

AKËKÕÖ

a. Àwôn ìwà tó ń mú ni jë ômôlúàbí

b. Sô àpççrç ìwà ômôlúàbí

d. Àýfààní tó wà nínú híhu ìwà bëê

e. Àpççrç ìwà tó lòdì sí ìwà ômôlúàbí

ç. Irú ewu tí ìwà bëê lè fà

f. Wàhálà tó lè dé bá ômôlúàbí àti bí ó śe lè borí ìśòro yìí.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI


  • Àwôn ìwé lítírèśõ tó dá lórí ìwà ômôlúàbí

  • Fídíò, fíìmù tó śe eré nípa ìwà ômôlúàbí

2.

ÀTÚNYÊWÒ LËTÀ ÀÌGBAGBÊFÊ

ÀKÓÓNÚ IŚË

  1. Rán àwôn akëkõö létí ìgbésê kíkô lëtà àìgbagbêfê

  2. Fún àwôn akëkõö ní orí-õrõ lëtà àìgbagbêfê

OLÙKÖ

a. Tö àwôn akëkõö sönà láti kô lëtà àìgbagbêfê.

b. Kô lëtà sí ilé-iśë rédíò kan nípa ire àti ibi tó wà nínú àśà ìgbàlódé tí àwôn õdö ń kó.

AKËKÕÖ

a. Sô oríśiríśi lëtà tó wà

b. Têlé ìlànà olùkö láti kô lëtà àìgbàgbêfê

d. Sô ìyàtõ tó wà láàrin lëtà gbêfê àti àìgbagbêfê



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

  • Pátákó tí a kô ìlànà lëtà kíkô sí

  • Ìwé àpilêkô lórí àròkô

3.

ÈDÈ: Ìsõrí õrõ

Àkóónú iśë

  1. Àlàyé lórí õrõ-àpèjúwe, õrõ-àpönlé, õrõ-atökùn àti õrõ-àsopõ

  2. Sísô ipò tí õkõõkan máa ń wà nínú ìhun gbólóhùn

OLÙKÖ

a. Sô iśë tí õkõõkan àwôn õrõ wõnyí máa ń śe nínú gbólóhùn

b. Kô àpççrç irúfë õrõ wõnyí sókè

d. Pe àwôn õrõ náà fún akëkõö



AKËKÕÖ

a. Dá àwôn ìsõrí õrõ yìí mõ nínú ìhun gbolohun

b. Pe àwôn õrõ náà bí olùkö śe pè wön.

d. Śe àwòkô àwôn õrõ tí olùkö kô sójú pátákó.



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

  • Kádíböõdù pélébé pélébé tí a kô àpççrç àwôn ìsõrí õrõ sí.

  • Ìwé atúmõ èdè Yorùbá

  • Pátákó ìkõwé àti çfun.

4.

LÍTÍRÈŚÕ:Kíkö ni mímõ:Iśë Òýkõwé Alátinúdá (Ewì, ìtàn àròsô, eré-onítàn)

ÀKÓÓNÚ IŚË

  1. Àtúnyêwò àwôn ìlànà tí òýkõwé ní láti kíyèsí fún kíkô ìwé alátinúdá

  2. Gbígbìyànjú láti kô ewì, ìtàn àròsô àti eré-onítàn kékèèké

OLÙKÖ

a. Śe àlàyé kíkún lórí kíkô ìwé alátinúdá.

b. Sô ìlànà ìgbékalê ìwé alátinúdá

d. Sô àwôn èròjà tó mú kí ìwé dùn

e. Jë kí akëkõö gbìyànjú àtikô ìwé àtinúdá

ç. Pípe àwôn gbajúmõ òýkõwé láti wá dá akëkõö lëkõö



AKËKÕÖ

a. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí kíkô ewì àtinúdá: ìlànà ìgbékalê, àtinúdá àti èròjà tó ń mú adùn bá ewì

b. Tëtí sí ìdánilëkõö láti õdõ gbajúmõ òýkõwé

d. Kô eré-onítàn àti ewì kékèèké.



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

  • Ìwé ìtàn àròsô

  • Ìwé eré-onítàn

  • Ìwé ewì

5.

ÀŚÀ: Ètò Çbí

ÀKÓÓNÚ IŚË

  1. Àlàyé lórí ohun tí à ń pè ní çbí

  2. Bàbá gëgë bí olórí çbí

d. Iśë òbí sí ômô àti iśë ômô sí òbí

e. Ìbáśepõ láàrin ômô ìyá sí ômô ìyá àti ôbàkan sí ôbàkan.

ç. Ìbáśepõ pêlú ìdílé ìyá çni àti bàbá çni

f. Ipò àti iśë tí çnìkõõkan ń śe nínú çbí.



OLÙKÖ

a. Sô oríkì çbí

b. Śàlàyé kíkún lórí ojúśe çnìkõõkan nínú çbí

d. Kô kókó pàtàkì pàtàkì sójú pátákó



AKËKÕÖ

a. Tëtí sí àlàyé olùkö

b. Béèrè ìbéèrè löwö olùkö

d. Dáhùn ìbéèrè olùkö

e. Śe àkôsílê ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI


  • Àwòrán

  • Fídíò

  • Tçlifísàn

  • Téèpù

6.

ÈDÈ: Aáyan Ògbufõ

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Ìtönisönà lórí bí a śe ń śe aáyan ògbufõ.

b. Túmõ àwôn õrõ àti èdè ewì láti èdè Gêësì sí Yorùbá.


OLÙKÖ

a. Śàlàyé bí a śe ń śe aáyan ògbufõ

b. Darí akëkõö láti túmõ àwôn õrõ àti èdè ewì tí a kô sójú pátákó láti èdè Gêësì sí èdè Yorùbá

d. Kô àwôn õrõ àti ewì tí a túmõ sí ojú pátákó.



AKËKÕÖ

a. Tëtí sí bí olùkö śe ń túmõ àwôn õrõ àti ewì.

b. Túmõ àwôn õrõ tí olùkö fún un sí èdè Yorùbá.

d. Kô àwôn ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé.



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

  • Ìwé tí a yàn

  • Ìwé atúmõ

  • Pátákó ìkõwé

7.

LÍTÍRÈŚÕ: Ewì Àpilêkô

ÀKÓÓNÚ IŚË

  1. Kókó õrõ

  2. Ìhun (ètò)

d. Ìlò èdè

e. Àśà àti ìśe tí ó súyô

ç. Àmúyç àti àléébù inú rê


OLÙKÖ

a. Jë kí akëkõö ka àśàyàn ewì tí ó mõ

b. Jë kí akëkõö ka àśàyàn ewì síta

d. Śàlàyé nípa àkóónú iśë bí ó śe súyô nínú ewì



  • Kókó õrõ

  • Ìhun

  • Ìlò èdè

  • Àśà tó súyô

  • Àmúyç àti àléébù

e. Kô àwôn õrõ tí ó śe pàtàkì tí ó súyô sójú pátákó pêlú àlàyé ìtumõ wôn

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

  • Àśàyàn ìwé àpilêkô

  • Pátákó ìkõwé.

8.

Ìtêsíwájú Eré Ìdárayá

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Oríśiríśi eré ìdárayá



    • Eré òśùpá, bojúbojú...

    • Eré abëlé – àlô pípa

    • Eré ìta gbangba, òkòtó títa, àrìn títa, ìjàkadì/ çkç àti bëê bëê lô

b. Eré òde òní

    • Böõlù gbígbá

    • Eré sísá

    • Díráfítì títa

    • Káàdì títa

    • Lúdò àti bëê bëê lô

OLÙKÖ

a. Śàlàyé bí a ti ń śe díê nínú eré ìdárayá tí a mënubà

b. Tö akëkõö sönà láti śe àwôn eré ìdárayá náà

d. Kô àwôn orin inú eré ìdárayá tó lórin sójú pátákó

e. Tö akëkõö sönà láti sô àwôn àýfààní àti ewu tí ó wà nínú eré náà

AKËKÕÖ

a. Tëtí sí àlàyé olùkö

b. Sô ohun tí o mõ nípa eré ìdárayá śáájú ìdánilëkõö

d. Kópa nínú śíśe eré ìdárayá náà

e. Béèrè ìbéèrè

ç. Śe àkôsílê ohun tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

  • Àwòrán ohun èlò gidi: ôpön ayò, lúdò, díráfíìtì àti bëê bëê lô

  • Àwòrán agbáböõlù àti bëê bëê lô

9.

ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ ÀRÀNMÖ

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Oríkì àrànmö

b. Àrànmö ohùn

d. Àrànmö Fáwëlì

e. Àrànmö iwájú

ç. Àrànmö êyìn

f. Àrànmö aláìfòró àti àrànmö afòró


OLÙKÖ

a. Śàlàyé fún àwôn akëkõö ohun tí àrànmö jë

b. Sô oríśiríśi àrànmö tí ó wà pêlú àpççrç tí ó múná dóko

d. Béèrè ìbéèrè löwö akëkõö

e. Śe àkôsílê sójú pátákó

AKËKÕÖ

a. Tëtí sí olùkö

b. Béèrè ìbéèrè löwö olùkö

d. Dáhùn ìbéèrè olùkö

e. Śe àkôsílê sínú ìwé rç

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI


  • Pátákó ìkõwé

10.

ÀTÚNYÊWÒ ÈTÒ ÌŚÈLÚ

ÀKÓÓNÚ IŚË

  1. Ààtò agbo-ilé

  2. Ètò oyè jíjç

    • oyè ìdílé

    • Oyè ìfidánilölá

d. Ètò ìśèlú òde òní:

  • Ìjôba àpapõ

  • Ìjôba ìpínlê

  • Ìjôba ìbílê

OLÙKÖ

a. Śàlàyé ààtò agbo-ilé

b. Śàlàyé ní kíkún lórí oyè jíjç àti oríśiríśi tó wà

d. Sô nípa ìśèlú òde òní fún àwôn akëkõö



AKËKÕÖ

a. Sô àwôn tó ń kópa nínú àtò agbo-ilé

b. Sô ipa akópa kõõkan tí wön dárúkô ní (a)

d. Sô oríśiríśi oyè tí ó wà ní àwùjô

e. Śàlàyé ìjôba àpapõ àti ìbílê

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI


  • Fídíò ayçyç ìfinijoyè

11.

LÍTÍRÈŚÕ: Àtúpalê àśàyàn ìwé ìtàn àròsô méjì

ÀKÓÓNÚ IŚË

  1. Kókó õrõ

  2. Àhunpõ ìtàn

d. Ìfìwàwêdá

e. Ibùdó ìtàn

ç. Ôgbön ìsõtàn

f. Àśà tí ó súyô

g. Àmúyç àti àléébù


OLÙKÖ

a. Mójú tó àwôn akëkõö láti kàwé ìtàn àròsô

b. Śàlàyé àhunpõ ìtàn, ìfìwàwêdá, ibùdó ìtàn, ôgbön ìsõtàn àti ti àśà tó súyô.

d. Jíròrò pêlú akëkõö láti sô àmúyç àti àléébù inú àwôn ìtàn tí wön kà.



AKËKÕÖ

a. Ka ìwé ìtàn àròsô méjèèjì

b. Śe àtúnsô ìtàn inú ìwé ìtàn àròsô tí wön kà ní sókí

d. Jíròrò lórí ìfìwàwêdá, ibùdó ìtàn àti ôgbön ìsõtàn.

e. Sô àwôn àśà tó súyô nínú ìtàn tí wôn kà.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI


  • Ìwé ìtàn àròsô tí a yàn

  • Àwòrán tí ó bá lè jëwö ìśêlê inú ìwé ìtàn àròsô tí a yàn.

12.

ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ ÌGBÉYÀWÓ, ÌSÌNKÚ ÀTI OGÚN JÍJÇ

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Àtúnyêwò ìsìnkú ìbílê

b. Ìsìnkú ômôlëyìn Kírísítì, Mùsùlùmí àti bëê bëê lô

d. Àtúnyêwò ogún jíjç ní ìlànà ìbílê

e. Ogún jíjç ní ìlànà ìgbàlódé


OLÙKÖ

a. Jíròrò pêlú àwôn akëkõö lórí ìsìnkú ìbílê

b. Śàlàyé ìsìnkú ômôlëyìn Kírísítì, Mùsùlùmí àti bëê bëê lô

d. Śàlàyé ogún jíjç ní ìlànà ìbílê

e. Śàlàyé ogún jíjç ìgbàlódé

AKËKÕÖ

a. Śe àbêwò sí ibi ìsìnkú ìbílê

b. Śe àbêwò síbi ìsìnkú ômôlëyìn Kírísítì àti ti Mùsùlùmí

d. Śe ìròyìn ojúmi to fún àwôn çlçgbë wôn lórí àbêwò wôn sí irúfë ìsìnkú mëtêêta.



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

  • Àwòrán ìjókòó àwôn àgbà níbi tí wön ti ń pín ogún

  • Àwòrán àwôn tó gbé òkú tí wön ń tu adìyç ìrànà níwájú rê.

  • Fídíò ìsìnkú àti àsìkò ogún pínpín.

13.

ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ




14.

ÌDÁNWÒ




YORÙBÁ SS 3 TÁÀMÙ KEJÌ

ÕSÊ

ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ

ÀMÚŚE IŚË


1.

ÈDÈ: Àtúnyêwò gbogbo ìsõrí gbólóhùn, ìpàrójç àti ìsúnkì

ÀKÓÓNÚ IŚË

a. Gbólóhùn abödé, gbólóhùn oníbõ, alálàyé, ìbéèrè àti àśç, gbólóhùn alákànpõ, oníròyìn, alátçnumö àti gbólóhùn ìyísódì

b. Oríkì ìpajç, òfin ìpajç, fáwëlì àti köńsónáýtì pípajç

d. Ìyöpõ fáwëlì

e. Oríkì ìsúnkì

ç. Ìbáśepõ tí ó wà láàrin ìpajç àti ìsúnkì.



OLÙKÖ

a. Śàlàyé oríśiríśi ìsõrí gbólóhùn

b. Śàlàyé ìyàtõ tí ó wà láàrin gbólóhùn kõõkan

d. Sô oríkì ìpajç, ìsúnkì àti ìyöpõ fáwëlì

e. Sô òfin tí ó de ìpajç, ìsúnkì àti ìyöpõ fáwëlì

ç. Béèrè ìbéèrè löwö akëkõö

f. Yán kókó sójú pátákó

AKËKÕÖ

a. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí oríśiríśi ìsõrí gbólóhùn àti ìyàtõ wôn.

b. Da àwôn àpççrç ìsõrí gbólóhùn tí olùkö kô sójú pátákó kô sínú ìwé

d. Béèrè ìbéèrè löwö olùkö

e. Dáhùn ìbéèrè olùkö

ç. Śe àkôsílê sínú ìwé rç



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

  • Pátákó ìkõwé

2.

ÀŚÀ: Àtúnyêwò àwôn õnà ìbánisõrõ

  1. Àrokò: oríśiríśi

  2. Oríśiríśi õnà tí a lè gbà pàrokò

  3. Ìyàtõ láàrin ìpàrokò láyé àtijö àti òde òní

  4. Ìwúlò àrokò

ÀKÓÓNÚ IŚË

  1. Ohun tí ìbánisõrõ jë

  2. Oríśiríśi õnà ìbánisõrõ láyé àtijö

d. Oríśiríśi õnà ìbánisõrõ láyé òde òní.

e. Pàtàkì sísô èdè abínibí



OLÙKÖ

a. Śàlàyé ohun tí ìbánisõrõ jë

b. Śàlàyé oríśiríśi õnà ìbánisõrõ tí ó wà láyé àtijö àti òde òní

d. Śàlàyé ìdí tí sísô èdè abínibí fi pôn dandan.



AKËKÕÖ

a. Sô ohun tí ìbánisõrõ jë

b. Sô oríśiríśi õnà ìbánisõrõ láyé àtijö àti òde òní

d. Sô õrõ láwùjô

e. Jíròrò lórí ìdí tí a fi gbödõ máa sô èdè Yorùbá.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI


  • Àwòrán àmì ìpàrokò bí i owó çyô, ìkarahun ìgbín, ìgbálê, ìyarun àti bëê bëê lô

  • Àwòrán àwôn àmì àrokò tòde òní

  • Fídíò çni tí ó ń sõrõ láwùjô.

3.

LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn àwôn ìwé ewì alohùn (ìwé méjì)

ÀKÓÓNÚ IŚË

  1. Kókó õrõ inú àwôn ewì alohùn náà

  2. Ìlò èdè inú àwôn ewì alohùn náà

d. Àśà àti ìśe Yorùbá tó súyô nínú àwôn ewì alohùn náà

e. õgangan ìró ewì alohùn tí a kà.



  • Àwôn akéwì (êsìn/ iśë wôn)

  • Ìlù, ijó ti wön ń lù sí i.

  • Àkókò tí wön máa ń lo ewì náà

  • Kíké àwôn ewì alohùn náà

OLÙKÖ

a. Śe àlàyé kókó õrõ àwôn ewì alohùn náà fún akëkõö

b. Śe àlàyé ìlò èdè inú àwôn ewì náà

d. Tç êrô fídíò fún wôn tàbí darí akéwì alohùn láti ké àwôn ewì náà

e. Tö akëkõö sönà láti ké ewì bí i méjì tàbí mëta láti inú àwôn ewì alohùn ìwé wôn

ç. Fa àśà Yorùbá tó jçyô nínú ewì náà



OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

Ìwé ewì alohùn tí a yàn

Fídíò àti fönrán tí a gba ewì alohùn sí

Akéwì alohùn



4.

Ìdánwò




TECHNICAL DRAWING

SSS 3 FIRST TERM


WEEK

TOPIC / CONTENT

ACTIVITIES

1

FREE HAND SKETCHING AND DRAWING

principles of free hand sketching of hand tools used by builders and engineers e.g. hammer plurs saws, spanners etc



Teacher

explain the principle of free hand sketching

guides student in sketching in stitching hand tools

students:

make free hand sketches of hand tool



teaching materials:

hand tools posters.




2

ENGINEERING DESIGNS AND WORKING DRAWING

engineering design process and preparation of working drawing e.g. plans elevations etc

teacher:

explains engineering design processes

guides students to design useable engineering items e.g. funnels, opener sparer etc

guides student in the preparation of engineering working drawings



student:

select and deign a useable engineering item

preparer the working drawing of chosen item

teaching materials

drawing instruments and model




3

SCREW THREADS, FASTENER AND DEVICES

type of screw threads e.g. v-threads ,square buttress and active etc

type of fastener and their user e.g. bolt, nuts, studs screws etc


teacher:

display and describes type of screw threads

and fasteners

students:

identify type of screw threads and fasteners



teaching materials

bench vice, bolts, screws nuts etc .




4

SCREWS THEADS FASTENERS AND DEVICES

Type of locking devices and their application e.g. lock nut washers, slotted nut keys, spines



Teacher:

Guides student in the conventional represent of locking devise fastener and screw threads



Students:

Draw screw threads fasteners and locking devices using conventional symbols



Teaching Materials:

Lock nut scoffed nut keys, spines and pins




5

ENGINEERING WORKING DRAWINGS.

Example of machine parts e.g. brackets, sleeves cylinders etc




Teacher:

Guides student to prepare working drawing of simple machine parts e.g. crank and pedal



Student;

Prepare working drawing of simple machines past



Teaching materials

Crank and pedals




6

ENGINEERING WORKING DRAWINGS

Example of machine pasts e.g. block piston, connecting rod etc



Teacher:

Guides students to prepare working drawing s of simple machine parts eg piston, crank and commenting rod



Student :

Prepare work drawing of simple machines parts



Teaching Materials:

Piston, connecting rod crank




7

ENGINEERING WORKING DRAWINGS

Machine assemblies e.g. parallel clamps, water taps



Teacher:

Guides students to prepare working drawings of machine assembles to incarnate bolts and nuts.



Students;

Prepare working drawing of machine assemblies



Teaching materials:

Parallel clamps. Water tap.




8

ENGINEERING WORKING DRAWINGS

Machine assemblies e.g. bearing barring bracket and pulley



Teacher:

Guides student to prepare working drawings of machine assemblies to incorporate locking devices e.g. keys



Students:

Prepare working drawings of machine assemblies



Teaching Materials:

Bearing bracket and pulley




9

SECTIONS AND SECTION L VIEWS

Type of section revolving section off centre etc.



Teacher:

Guides the students to draw sectional view of machine part and assemblies



Students: draw various sectional views of machine parts and assemblies.

Teaching materials.

Diagrams, figures and charts.




10

SECTION AID SECTION L VIEWS

Sectional view of buildings



Teacher:

Guild student to draw sectional view of a building



Students

draw the sectional views of a building



Teaching materials:

Building drawings and models.




11

SECTION AND SECTIONAL VIEW

Sectional view of machine components



Teacher:

Guilds student to draw sectional views of a machine component



Student:

Draw the sectional views of a machine component



Teaching material:

Machine parts and models.



12

Revision

Revision

13

Examination

Examination

14

Examination

Examination



Download 2.23 Mb.

Share with your friends:
1   ...   9   10   11   12   13   14   15   16   ...   26




The database is protected by copyright ©ininet.org 2024
send message

    Main page